...
Flat Preloader Icon

KÍ LẸ Ò LÈ ṢE? (WHAT CAN YOU NOT DO?)

$10.00

The lyrics go thus:

Ki lẹ ò lè ṣe ? (What can you not do ?)

Kí lẹ ò lè ṣe Ọlọ́run mi, Kí lẹ ò lè ṣe ? Ẹ̀yin tí ẹ dà ayé àtọ̀run, Kí lẹ ò lè ṣe?

Kí lẹ ò lè ṣe? Ọlọ́run mi, Kí lẹ ò lè ṣe ?

Ta lẹ ò jù lọ, Ọlọ́run mi ta lẹ ò jù lọ ? Ẹyin tí ẹ dá ayé àtọ̀run, ta lẹ ò jù lọ? Ta lẹ ò jù lọ, Ọlọ́run mi ta lẹ ò jù lọ ?

 

Category:

Music Description

The Yorùbá people:Ọmọ Káàárọ̀-oòjíire.

One of the three largest ethnic groups of Nigeria, in West Africa. Concentrated in the southwestern part of the country. Much smaller, scattered groups live in Benin and northern Togo. The Yorùbá numbered more than 35 million at the turn of the 21st century, making them one of the largest Ethnic groups in Africa. Yorùbá people speak Yorùbá Language.

 

The lyrics go thus:

Ki lẹ ò lè ṣe ? (What can you not do ?)

Kí lẹ ò lè ṣe Ọlọ́run mi, Kí lẹ ò lè ṣe ? Ẹ̀yin tí ẹ dà ayé àtọ̀run, Kí lẹ ò lè ṣe?

Kí lẹ ò lè ṣe? Ọlọ́run mi, Kí lẹ ò lè ṣe ?

Ta lẹ ò jù lọ, Ọlọ́run mi ta lẹ ò jù lọ ? Ẹyin tí ẹ dá ayé àtọ̀run, ta lẹ ò jù lọ? Ta lẹ ò jù lọ, Ọlọ́run mi ta lẹ ò jù lọ ?

 

English Translation from the Yorùba Language

What can you not do, my God? What can you not do?

You, who created the earth and heavens what can you not do?

What can you not do my God? What can you not do?

Are you not the Most High? My God, are you not the Most High? You, who created the earth and the heavens, are you not the Most High? Are you not the Most High my God? Are you not the Most High?

 

Level: Intermediate

Category: Guitar Ensemble

ISMN: 979-0-807300-29-8

TE: 37

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “KÍ LẸ Ò LÈ ṢE? (WHAT CAN YOU NOT DO?)”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Seraphinite AcceleratorBannerText_Seraphinite Accelerator
Turns on site high speed to be attractive for people and search engines.